11/11/2015

ASOFIN EGBE PDP DARI ILE IGIMO ASOFIN AGBA



Fun igba akoko lehin ìfilọ́lẹ̀ ile igbimo asofin kejo, Igbákeji Aare ile igbimo naa, Ike Ekweremadu, ni o dari eto Newsday jabo.
Ohun ti o sele yii ni igba akoko ti asofin lati egbe alatako yio maa dari ile igbimo naa lati odun 1999 ti orilèdè Naijiria ti pada si ijoba tiwańtiwa. Ekweremadu ni o je omo egbe oselu peoples Democratic Party (PDP).
Ekweremadu dari eto ni ile igbimo naa ni ojo ojoru osu Kokanla odun ti a wa yii nigba ti Aare ile igbimo naa, ogbeni saraki lo si ile ijoba lati mojuto iburawole awon minisiter titun ti Aare orilèdè, Muhammadu Buhari sese yan sipo.
Ohun ti o sele yii ko dun mo awon Asofin kan ninu egbe APC ninu. Awon Asofin ti inu won ko dun naa ni won fi ehanu won han nipa kiko ara won kuro nibi ipade ile igbimo naa. Awon asofin egbe All Progressive Congress(APC) ti o jade ni ibi ipade naa ni Asofin Ahmed Lawan ati George

No comments:

Post a Comment