11/11/2015

AARE NIJIRIA LE AKON AKOWE IJOBA.



Aare orilèdè Naijiria ni o ti le awon akowe ijoba kan, ti o tin sise ni awon osu die sehin lenu ise. Eleyi ni o ṣàfihàn pe awon die ni o maa yan si awon ipo.
Iroyin lati aare ni ojo isegun ni o fihan pe eniyan meedogbon ni won maa gba si enu ise ninu awon ogoji.
Awon akowe ijoba ti a le naa ni o tin dari orisirisi eka ijoba ti on mojutó́ orisirisi eto ni orilèdè iyen awon ministry lati osu karun ti Aare Muhammadu Buhari ti gba ijoba.
Awon oloselu ti o mo nipa eto naa ni o so wipe minisiter meedogbon nikan ni o maa wa ninu ijoba titun naa.

No comments:

Post a Comment