Awon olopaa orilèdè Germany ti ri oku awon
omo ti o to meje ni ilu kan ti o sunmo enu ibodè CZech. Gege bi iroyin, awon
olopaa ni o ri oku awon omo naa nigba ti obirin kan ni agbegbe naa fariwo ta.
Oku awon omo naa ni won se ayẹwo re lowo,
nigba ti ohun ti o sokùnfà iku awon omo naa tabi igba ti won ku ko daju.
No comments:
Post a Comment