Orilèdè lebanon nio ti ya ojo oni soto lati
sofo awon ti o ku ninu ibugbamu ado oloro ni orilèdè naa. Gege bi iroyin,
awon ti o to mokanlelogoji ni o ti ku ninu isele naa nigba ti awon ti o ju igba
si farapa. Ninu isele naa ti ado oloro meji ti ado oloro meji ti bu léraléra
ni egbe ajijagbara jihaadi ni, ISIS so wipe awon làwon wa nidi e. Isele naa ni
o waye ni oja kan ni agbegbe gusu beirut.

No comments:
Post a Comment