13/11/2015

O MA SE O! OBIRIN OMO ODUN METADINLOGBON KAGBAKO IKU OJIJI LOWO OREKUNRIN RE.Obinrin omo odun metadinlogbon kan, Ladi Moses, ti on gbe ni agbegbe old Nigerian prison, wadata, markurdi ni o ti dágbére fayé ni ilé iwosan ti o tii n gba itoju. Omobìnrin naa ni a gbo wipe orekunrin re ti gbogbo aye mo si “Baba” ni o da asiidi sii lara ni ojo kewa, osu kokanla odun ti a wa yii, ti omobìnrin naa si ti dero ilé iwosan lati igba naa. Gege bi awon toro naa soju won se so, Baba ti o je orekunrin Ladi ni o pe omobìnrin naa jade lati inu ile bi eni pe awon ni oro pataki lati so, sugbon bi omobìnrin naa ti sunmo ni Baba yo igo kan ti awon eniyan gbagbo pe asiidi lo wa ninu re jade lapo re ti o si da nnkan ti o wa ninu re le omobìnrin naa lori ki o to fese fe. Gege bi iroyin ti o te wa lowo, omokùnrin naa ni won pada mu ni ibudo awon oloko nigba ti o fe wo oko ti yio gbe kuro ni markurdi. Afurasi odaran naa ni won ti fa le eka ajo olopaa “A” Division lowo nibi ti won tii n forowalenuwo lori isele naa. Alukoro ajo olopaa, Matthew Oku, ni o fidi isele naa mule ti o si so wipe awon ko ti gbo nnkan kan nipa iku omobìnrin naa lati ile iwosan ti o tii n gba itoju.Obinrin omo odun metadinlogbon kan, Ladi Moses, ti on gbe ni agbegbe old Nigerian prison, wadata, markurdi ni o ti dágbére fayé ni ilé iwosan ti o tii n gba itoju. Omobìnrin naa ni a gbo wipe orekunrin re ti gbogbo aye mo si “Baba” ni o da asiidi sii lara ni ojo kewa, osu kokanla odun ti a wa yii, ti omobìnrin naa si ti dero ilé iwosan lati igba naa. Gege bi awon toro naa soju won se so, Baba ti o je orekunrin Ladi ni o pe omobìnrin naa jade lati inu ile bi eni pe awon ni oro pataki lati so, sugbon bi omobìnrin naa ti sunmo ni Baba yo igo kan ti awon eniyan gbagbo pe asiidi lo wa ninu re jade lapo re ti o si da nnkan ti o wa ninu re le omobìnrin naa lori ki o to fese fe. Gege bi iroyin ti o te wa lowo, omokùnrin naa ni won pada mu ni ibudo awon oloko nigba ti o fe wo oko ti yio gbe kuro ni markurdi. Afurasi odaran naa ni won ti fa le eka ajo olopaa “A” Division lowo nibi ti won tii n forowalenuwo lori isele naa. Alukoro ajo olopaa, Matthew Oku, ni o fidi isele naa mule ti o si so wipe awon ko ti gbo nnkan kan nipa iku omobìnrin naa lati ile iwosan ti o tii n gba itoju.


Obinrin omo odun metadinlogbon kan, Ladi Moses, ti on gbe ni agbegbe old Nigerian prison, wadata, markurdi ni o ti dágbére fayé ni ilé iwosan ti o tii n gba itoju.
Omobìnrin naa ni a gbo wipe orekunrin re ti gbogbo aye mo si “Baba” ni o da asiidi sii lara ni ojo kewa, osu kokanla odun ti a wa yii, ti omobìnrin naa si ti dero ilé iwosan lati igba naa.
Gege bi awon toro naa soju won se so, Baba ti o je orekunrin Ladi ni o pe omobìnrin naa jade lati inu ile bi eni pe awon ni oro pataki lati so, sugbon bi omobìnrin naa ti sunmo ni Baba yo igo kan ti awon eniyan gbagbo pe asiidi lo wa ninu re jade lapo re ti o si da nnkan ti o wa ninu re le omobìnrin naa lori ki o to fese fe.
Gege bi iroyin ti o te wa lowo, omokùnrin naa ni won pada mu ni ibudo awon oloko nigba ti o fe wo oko ti yio gbe kuro ni markurdi. Afurasi odaran naa ni won ti fa le eka ajo olopaa “A” Division lowo nibi ti won tii n forowalenuwo lori isele naa.
Alukoro ajo olopaa, Matthew Oku, ni o fidi isele naa mule ti o si so wipe awon ko ti gbo nnkan kan nipa iku omobìnrin naa lati ile iwosan ti o tii n gba itoju.

No comments:

Post a Comment