Opolopo eniyan ti iye won ko din ni ogorun ni a gbo pe o ti dagbere Faye ninu orisirisi akolu ti o waye ni olu-ilu orilede faranse,iyen Paris,ni ale ojo eti, ojo ketala,OSU kokanla odun 2015.
Akolu naa ni a gbo pe o waye ni orisirisi ibi ni orilede naa, paapa ibi ti awon eniyan maa n po si ni ale ojo eti. awon ajo olopaa ni o so wipe awon ajo to n mojuto abo ilu pa meji ninu awon ti o sakolu naa.
Awon akolu naa ni a gbo pe o waye ni ile ounje kan ni 10th and 11th Arrondissement, Bataclan concert hall, ati papa-isere gbogboogbo(National Stadium). Awon olukoluni naa ni a gbo pe won ko tii mu nigba ti a nko iroyin yii Jo.
Aare orilede naa, François Hollande ni o ti kede eto konile gbe le e(state of emergency) kakiri gbogbo agbegbe naa titi won a fi ri awon odaran naa mu.
No comments:
Post a Comment