Awon ole kan ti won fi ohun ija oloro pamo
sinu búrẹdì ja awon eniyan lole ni ajo olopaa ipinle Rivers ti fi panpe oba
gbe. Oga olopaa ipinle naa, Musa Kimo fi awon aworan awon adingunjale naa han
lori ero ayélujára “facebook”. O le wo awon aworan naa nisale.
No comments:
Post a Comment