17/11/2015

OWO TE AWON AFURASI AJINIGBE MEJI NI BENIN



 Awon okunrin meji kan ni owo ti te pelu esun ijinigbe ati fifi ipa ba awon omode kunrin ti ko ju omo odun marundinlogun lopo. Awon afurasi naa ni owo awon vigilante te ni ibi ipamo won ni ilu Benin, ipinle Edo. Awon aworan awon afurasi naa wa nisale.



 

No comments:

Post a Comment