Awon asasala Syria kan ti iye won ko din ni
ogorun ni o ti bale ni U.K ninu eto ti ijoba U.K gbe kale. Awon eniyan naa ti a
yan kaakiri awon ipago/ibudo awon asasala (refugee camps) ni arin ila-orun ni o bale ni papa oko
òfurufú Glasgow ni nnkan bi aago merin
ku ogun iseju ni irole yii.
Awon eniyan naa ni o je akoko ninu awon bii
egberun lona ogun (20,000) ti ijoba U.K
pinu lati ko ki odun 2020 to koja.
Gege bi iroyin lati U.K, ijoba ti sa gbogbo
ipa won lati pàna gbogbo ewu to le fe gba ona yii wole ati wipe awon bi
egberun ni ijoba ni ireti pe yio wo orilèdè awon ki keresi(christmas) to koja.
No comments:
Post a Comment