Aare orilèdè Naijiria ni iroyin fihan pe o
ti setan lati kede awon oluranlowo pataki fun ijoba. gege bi iroyin ohun, awon
ti aare fe yan sipo ni o ti ni oruko won lowo ti yio si kede oruko won laipe. Bi
a ko ba gbagbe, oluranlowo pataki kan ni ijoba ti yan lati igba ti aare ti bere
ise. Oruko oluranlowo pataki naa ni Femi Adesina, eni ti o je oluranlowo fun
ijoba lori eto iroyin(NEWS AND
PUBLICITY).
No comments:
Post a Comment