15/11/2015

AGBABOOLU MARUN YIO DUPO AGBABOOLU TO DARA JU NI ORILEDE ALAWO DUDU



Oruko awon agbaboolu marun ti yio dupo Agbaboolu ti o dangajia ju ni awon orilèdè alawo dudu, eyi ti BBC sagbateru re, iyen, ”BBC African footballer of the year Award’’ ni o ti jade. Oruko awon agbaboolu naa ni Andre Ayew(Ghana), Yacine Brahimi(Algeria), Pierre -- Emeric Aubameyang(Gabon), Yaya Toure(Ivory coast) ati Sadio Mane(Senegal).
Eni ti yio gba ade naa ni awon olólùfè ere boolu orilèdè alawo dudu yio dibo yan. Idibo naa ni yio dópin ni ojo ogbon, osu kokanla, odun yii.
Oruko eniti o jawe olúborí ni won yio kede re ni ojo kokanla osu kejila odun yi.
Yacine Brahimi
Andre Ayew
Image for the news result
Sadio mane

Image result for pierre emerick aubameyang
pierre emerick aubameyang
Image result for yaya toure
Yaya Toure

No comments:

Post a Comment