A RI AMAECHI NI SENATE
Gomina
ana ipinle Rivers, Rotimi Amaechi ni a
le forowalenuwo leni ojo kejilelogun, osu kewaa odun 2015. Agbenugo awon asofin
ile wa, Dino Melaye lo fi oro ohun to awon oniroyin leti. Gege bo se so, esi iwadi
awon eka iwa ati anfaani {Ethics and privileges committe} lori oro gomina ana naa ni won yio gbe kale siwaju
awon asofin ile wa loni. Bi a ko ba gbagbe, okunrin gomina ana naa ni a ti yo
oruko re kuro laarin awon ti a o fi oro walenuwo mi opolopo igba ki o to di
oni. Amaechi, eni ti won fesun kan wipe o ji billionu lona aadorin naira nigba
ti o wa ni ipo gomina ipinle Rivers.
Iforowanilenuwo
Amaechi ni awon asofin ti gbe pati ni igba meta ototo, sugbon ireti wa pe yio
see se ni oni.
No comments:
Post a Comment