AWON
OMO NAIJIRIA JAWE OLUBORI NINU IFESEWONSE KEJI IDIJE AGBAYE
Awon oje wewe Naijiria ti on sasoju orilèdè yi ni ìdíje Agbaye
boolu alafesegba awon omo ti ojo ori won ko ju metadinlogun ni won ti tesiwaju
si ipele keji ìdíje naa nigba ti won orilèdè chile, ti on gbàlejò ìdíje
naa pelu ami ayo marun si okan. Samuel Chukwueze ati Victor Osimhen ju goolu
meji meji sàwon nigba ti kelechi Nwakali
gba okan sàwon. Meji ninu goolu ohun ni oje koju simi kin gba
si o (penalty). Marcelo Allende ni o gba goolu kan wole fun chile nigba ti a le
Funsho Bamgboye jade. Naijiria ni o ti wa tesiwaju si ipele awon merindinlogun
(round of 16)
No comments:
Post a Comment