20/11/2015

EGBE TI O SOMO AL- QAEDA SO WIPE AWON LO WA NIDI AKOLU MALI.



Awon egbe Al- Mourabittoun, egbe kan ti on satileyin fun egbe apani laya Al – Qaeda ni o ti so wipe awon làwon wa nidi akolu ti o waye ni Bamako, olu ilu orilede Mali  ni  ana. Gege bi iroyin ti fihan, awon iko kan ti o je bi eniyan mewa ni o sakolu si Radisson Blu Hotel ti won si se awon bii Aadosan monu ile ìtura naa. Iroyin ni p fihan pe oku eniyan bii mejidinlogun ni won gbe jade ninu ile ìtura naa, nigba ti omo orilèdè Belgium kan ku ninu igbiyanju lati gba awon ti a semo sile.


No comments:

Post a Comment