20/11/2015

OKO AJAGBE DANGOTE NI IJAMBA OKO NI ASABA.



Oko ajagbe elejo Dangote kan ni o ni ijamba oko ni oju ona marose Asaba si Onitsha ni osan oni. Gege bi iroyin se so, oko naa ni o kolu opolopo oko ki o to gbaná ti awon bii mewa si jọ́nà ku. Awon panápaná ni o ri ina naa pa ki o jọ́nà koja ala, sugbon ijamba naa fa sunkere awon oko loju ona ohun.


 

 

No comments:

Post a Comment