20/10/2015

Emenike Fi eagles sile



Emenike Feyin tì Ninu Iko Agba-boolu Super Eagles.
Idaamu ti o ti subu lu egbe agbaboolu Super Eagles ni o ti gbo ná mi yo nigba ti Atamátàsé Emmanuel Emenike kede ifeyinti ninu egbe na.
Ere agó (Premium times)  ijabo wipe atamátàsé ti on gba bo olu jeun ni Al Ain tile Du bai, awon ti o ya lowo fenerbahce, ni o kede ifeyinti re lori ero ayélujára instagram ni ale ojo aje.
O si wi: "Ko si ìtẹ̀síwájú sii ni Eagles! Lehin odun marun nla, inu mi dun lati kede wipe mo ti fi idan ìdúró si gbigba bo olu fun orile dé mi, ki alaafia le joba. "
"O ni idunnu ni oje  fun mi lati gba bo olu fun orile dé la yii. Mi ò kabamo, Mo si ro pe o ti to akoko lati fi ìparí si ohun gbogbo. opolopo ope si gbogbo awon egbe afenifere ti o satileyin fun wa, Nigba akoko ti o dara ati buburú igba.
Emmanuel Emenike
Emmanuel Emenike
"inu mi dun si ise mi (performance) ni gbogbo akoko yii, inu mi dun si awon omo egbe mi, inu mi si dun si orile dé mi, Naijiria. Àseyege mi ni AFCON je ohun la, eye agbaboolu to ju bo olu sàwon ju ti mo gba na si je ohun amu yangan ti o fi ife mi han si egbe na."
Gege bi agbaboolu na ti so, egbe agbaboolu, egbe orile dé kii se ti enikan, nitorina, ko si enikan to yé ki o wa ni ewu.
"Super Eagles je ibudo, kii se ile ebi(family house), ko si ye ko je ibi ewu fun enikeni.
"Mo ti ṣe gege bi orilẹ-iyin (national anthem). "Gbogbo àlá mi wà si imuse ninu egbe orile-ede, mo la alà lati gba ife-eye ŃATIONS CUP fun Naijiria, lehin ogun odun, mo la alà lati gba bo olu ni ìdíje ti gbogbo agbaye lati fi oruko mi lele,  ni aarin odun marun, gbogbo re wa si imuse, Asegun ni mi!!!
"Fun gbogbo omo egbe alatieyin ti inu won ko dun si igbese mi, boya nitori mo ko lati tun ma ju bo òlu sàwon, ma so wipe ki e ma binu, awon ti mo ju sàwon se daadaa fun egbe na.
" bi naijiria ba si tin wa, gbogbo wa ni a o ma ranti oruko 'Emenike'. "Níkẹyìn, inu mi dun lati teriba, maa si ma satileyin fun egbe na ni gbogbo igba." Bayi ni o si pari oro re.
Emenike wà lara awon egbe Naijiria ti o gba ami eye ìdíje koopu ile Afrika ni 2013 ni orile dé South Afrika.

No comments:

Post a Comment