Bi a ko ba gbagbe, orilèdè naa ni ajo WHO ti
kede pe o bo lowo arun Ebola nigba meji ki o to di akoko yii, ti o si je pe ni
igba mejeeji ni arun naa pada jeyo.
Arun Ebola ni o ti pa egberun Mokanla o le
odunrun(11,300) eniyan lati igba ti arun
naa ti bere ni osu kejila odun 2013, eyi ti o mu akoko naa je igba ti arun naa
pa eniyan julo lati odun 1976 ti o ti di
mimo.
This comment has been removed by the author.
ReplyDelete