24/11/2015

Ojo Isegun, osu kokanla.



1939: Imperial Airways ati British Airways darapo lati di “British Overseas Airways corporation”.
1950: awon ologun UN kogun ti ìyókù North Korea, pelu ireti pe awon yio pari ogun Korea ko to             digba odun
1951: ile ise oko Morris ati Austin gba lati darapo.
1963: Jack Ruby yinbon lu Lee Harvey Oswald, eni ti won fi esun pipa John F Kennedy kan.
1977: orilèdè Greece kede pe awon ti sawari iboji King Philip 2, baba Alexander the Great.
1995: Ireland dibo 50.28% si 49.72% lati fi opin si ofin ti o tako ikorasile(divorce) ninu igbeyawo.
2012: ina ti o pa ju eniyan aadofa (110) jo ile ise aso kan ni Dhaka, Bangladesh.

No comments:

Post a Comment