24/11/2015

Gomina Kaduna ta oko fun awon ajo eleto aabo ipinle re.



Gomina Kaduna, Nasir El Rufai ni o ra oko oluso (patrol vehicle), metadinlaadofa(107) ati awon ohun elo mi ti o ye fun aabo ilu fun ajo olopaa ati awon ajo ti on mojuto eto aabo ni ilu naa. Gege bi iroyin se so, awon nnkan naa ni oga olopaa orilèdè̀, Solomon Arase, tewo gba nibi ayéye kan ni ipinle naa. Awo aworan lati ibi ayéye naa wa nisale.

No comments:

Post a Comment