21/11/2015

AWORAN IJAMBA OKO AJAGBE NI AGBEGBE JOS



Oko ajagbe elejo kan ti o ko awon eru kan ni o ti subu ni Hawan Kibbo, ni agbegbe oju ona marose aginjù Jos – Akwanga. Oko ohun ni o si fee di gbogbo oju ona.  Gege bi ileise ti on mojuto aabo oju popo se so, iyen ajo Road Safety, igbiyanju ti n lo lowo lati gbe oko naa kuro loju ona ohun.






No comments:

Post a Comment