21/11/2015

AKOLU ADO OLORO NI CAMEROON PA ENIYAN.



Awon ti iye won ko kere ju mejo ni ireti wa pe o ti gbẹmimi ni akolu ti o waye ni orilèdè cameroon ni irole oni. gege bi iroyin ti o te wa lowo, awon obinrin meta ati okunrin kan ti awon eniyan gbagbo pe won je omo iko Boko – Haraamu ni o ju awon ado oloro ti won fi pa ara won ati awon eniyan naa. Akolu na ni o waye ni abule Nigue, ni agbegbe fotokol, ni ihà ariwa orilede Cameroon.

No comments:

Post a Comment