21/11/2015

OBINRIN TI O KU NI PARIS KO NI O GBE ADO OLORO DANI.



Awon ti on sayewo eya ara awon oku ti o ku ni ile kan ti awon olopaa Paris gbogun ti ni ojo ojoru ni o ti fihan pe Hasna Aitboulahcen, obirin ti o ku ninu ile naa ko lo gbe ado oloro dani.
Iroyin ti o koko jade ni ose yii ni o sope obirin naa ni o gbe ado oloro dani, eyi ti o mu ko je obinrin akoko ti yio se iru ohun be ni ile alawo funfun(Europe), sugbon iwadii tuntun fihan pe awon meta ni o wa ninu ile naa, ati pe o see se ko ma je obirin naa ni o gbe  ado oloro naa dani.

No comments:

Post a Comment