01/12/2015

Ajo olopaa mu awon marun fun títò pase Aare ana



Ajo olopaa ipinle Bayelsa ni o ti fidi mimu awon omo egbe oselu All Progressive Congress (APC) marun mule lori esun pe won tele awon oko ti on ba aare ana, Dr. Goodluck Jonathan rin.
Gege bi iroyin se so, ajo olopaa naa ni o fihan pe awon eniyan naa ki se awon ajijagbara teleri (ex militant) gege bi awon eka iroyin kan se so. Asimin Butswat, ti o je alukoro ajo olopaa ipinle Bayelsa ni o fi eleyi han ninu oro re. Gege bo se so, awon eniyan naa ti o je omo egbe APC ni won sesi tele oko ti o gbe aare ana dani lero pe oga egbe won ni won tele.
 

No comments:

Post a Comment