23/11/2015

OJO KETALELOGBON, OSU KOKANLA(BELU) NINU ITAN.



Awon ohun ti o sele ni iru ojo oni ninu itan po ju eyi lo, sugbon iwọnba die ti a mu wa niyi.
1909: Awon arakunrin Wright (Wright Brothers) bere ile ise oko òfurufú(Air plane.) oni millionu kan dollar.
1968: Awon okunrin merin gba oko òfurufú orilèdè Amerika, pelu ero metadinlaadoru(87) laarin Miami si Cuba.
1980: Ile riru (Earthquake) ti o pa to eniyan egberun lona meta sele ni Italy, 1915 ni iru re ti  sele gbeyin ni gbogbo orilèdè Europe ki o to di akoko yii.
1992: Smartphone akoko, IBM Simon, ni a fihan ni COMDEX ni Las Vegas, Nevada.
2005: Ellen Johnson Sirleaf, wole ibo aare orilèdè Liberia, eyi ti o mu ko je obirin akoko ti o di aare ni gbogbo orilèdè Alawo dudu(Africa)

No comments:

Post a Comment