29/11/2015

Afurasi odaran ku sahamo EFCC



Afurasi odaran kan, Arowofela Olufemi ni o ti ku si ahamo ajo ti gbogun ti iwa jegudujera laarin ilu, iyen Economic and financial crime commission(EFCC). Gege bi iroyin se so, omokùnrin naa ni o ku ni nnkan bi aago marun abo ojo Abameta ojo kejidinlogbon osu yii leyin ti o so wipe aya n dun ohun ti o si dero ile iwosan. Omokùnrin naa ti won ti jabo iku re fun awon ara ile re ni enikeni ko tii mo ohun ti o sokùnfà iku re sugbon iwadi awon olopaa  n tesiwaju lori isele naa.
                                                                           

No comments:

Post a Comment